Jẹ́nẹ́sísì 39:10 BMY

10 Bí ó tílẹ̀ jẹ́ pé gbogbo ìgbà ni ó ń tẹnumọ́ èyí fún Jósẹ́fù, Jósẹ́fù kọ̀ láti bá a lò pọ̀. Ó tilẹ̀ kọ̀ láti máa dúró ni ibi tí ó bá wà.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 39

Wo Jẹ́nẹ́sísì 39:10 ni o tọ