Jẹ́nẹ́sísì 39:11 BMY

11 Ní ọjọ́ kan, Jósẹ́fù lọ sínú ilé láti ṣe iṣẹ́, kò sì sí èyíkéyìí nínú àwọn ìránṣẹ́ ní tòsí.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 39

Wo Jẹ́nẹ́sísì 39:11 ni o tọ