Jẹ́nẹ́sísì 39:12 BMY

12 Ó sì di aṣọ Jósẹ́fù mú, ó sì wí pé, “Wá bá mi lò pọ̀!” Ṣùgbọ́n Jósẹ́fù fi aṣọ rẹ̀ sílẹ̀ sí i lọ́wọ́, ó sì sá jáde.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 39

Wo Jẹ́nẹ́sísì 39:12 ni o tọ