Jẹ́nẹ́sísì 39:8 BMY

8 Ṣùgbọ́n Jósẹ́fù kọ̀, ó sì wí fún aya ọ̀gá rẹ̀ pé, “Kíyèsi, Olúwa mi kò fi ohunkóhun dù mi nínú ilé yìí, gbogbo ohun ìní rẹ̀ ni ó fi lé mi lọ́wọ́.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 39

Wo Jẹ́nẹ́sísì 39:8 ni o tọ