Jẹ́nẹ́sísì 40:14 BMY

14 Ṣùgbọ́n nígbà tí ohun gbogbo bá dára fún ọ, rántí mi kí o sì fi àánú hàn sí mi. Dárúkọ mi fún Fáráò, kí o sì mú mi jáde kúrò ní ìhín.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 40

Wo Jẹ́nẹ́sísì 40:14 ni o tọ