Jẹ́nẹ́sísì 40:16 BMY

16 Nígbà tí olórí alásè rí i wí pé ìtúmọ̀ tí Jósẹ́fù fún àlá náà dára, ó wí fún Jósẹ́fù pé, “Èmi pẹ̀lú lá àlá: Mo ru agbọ̀n oúnjẹ mẹ́ta lórí,

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 40

Wo Jẹ́nẹ́sísì 40:16 ni o tọ