Jẹ́nẹ́sísì 41:43 BMY

43 Ó sì mú un kí ó gun kẹ̀kẹ́ ẹsin bí igbàkejì ara rẹ̀, àwọn ènìyàn sì ń pariwo níwájú rẹ̀ pé, “Ẹ yàgò lọ́nà.” Báyìí ni ó sì fi ṣe alábojútó gbogbo ilẹ̀ Éjíbítì.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 41

Wo Jẹ́nẹ́sísì 41:43 ni o tọ