Jẹ́nẹ́sísì 41:44 BMY

44 Nígbà náà ni Fáráò wí fún Jóṣẹ́fù pé, “Èmi ni Fáráò. Ṣùgbọ́n láì sí àṣẹ rẹ, ẹnikẹ́ni kò gbọdọ̀ ṣe ohunkohun ní ilẹ̀ Éjíbítì.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 41

Wo Jẹ́nẹ́sísì 41:44 ni o tọ