Jẹ́nẹ́sísì 42:36 BMY

36 Jákọ́bù bàbá wọn wí fún wọn pé, “Ẹ ti mú mi pàdánù àwọn ọmọ mi. N kò rí Jósẹ́fù mọ́, bẹ́ẹ̀ ni n ò kò sì rí Símónì náà mọ. Ẹ sì tún fẹ́ mú Bẹ́ńjámínì lọ! Èmi ni gbogbo ohun búburú yìí wá ń ṣẹlẹ̀ sí.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 42

Wo Jẹ́nẹ́sísì 42:36 ni o tọ