Jẹ́nẹ́sísì 42:37 BMY

37 Nígbà náà ni Rúbẹ́nì wí fún bàbá rẹ̀ pé, “Pa àwọn ọmọ mi méjèèjì bí n kò bá mú Bẹ́ńjámínì padà wá fún ọ, èmi ni kí o fà á lé lọ́wọ́, n ó sì mu-un padà wá.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 42

Wo Jẹ́nẹ́sísì 42:37 ni o tọ