Jẹ́nẹ́sísì 42:38 BMY

38 Ṣùgbọ́n Jákọ́bù wí pé, “Ọmọ mi kì yóò bá a yín lọ, ẹ̀gbọ́n rẹ̀ ti kú, òun nikan sì ni ó kù nínú àwọn ọmọ ìyá rẹ̀. Bí ohunkóhun bá sẹlẹ̀ sí i, ìbànújẹ́ ni yóò sì pa mi kú ni ọjọ́ ogbó mi yìí.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 42

Wo Jẹ́nẹ́sísì 42:38 ni o tọ