Jẹ́nẹ́sísì 43:15 BMY

15 Nítorí náà wọ́n mú àwọn ẹ̀bùn náà àti owó ìlọ́po méjì àti Bẹ́ńjámínì, wọ́n sì yára lọ sí ilẹ̀ Éjíbítì, wọ́n sì fi ara wọn hàn níwájú Jóṣẹ́fù.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 43

Wo Jẹ́nẹ́sísì 43:15 ni o tọ