Jẹ́nẹ́sísì 43:16 BMY

16 Nígbà tí Jóṣẹ́fù rí Bẹ́ńjámínì pẹ̀lú wọn, ó sọ fún ìránṣẹ́ ilé rẹ̀, “Mú àwọn ọkùnrin wọ̀nyí lọ sí ilé mi, pa ẹran kí o sì se àsè; wọn ó jẹun ọ̀sán pẹ̀lú mi.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 43

Wo Jẹ́nẹ́sísì 43:16 ni o tọ