Jẹ́nẹ́sísì 45:15 BMY

15 Ó sì tún fẹnu ko gbogbo àwọn arákùnrin rẹ̀ lẹ́nu, ó sì sunkún sí wọn lára. Lẹ́yìn èyí, Jósẹ́fù àti àwọn arákùnrin rẹ̀ sọ̀rọ̀ pọ̀.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 45

Wo Jẹ́nẹ́sísì 45:15 ni o tọ