Jẹ́nẹ́sísì 45:16 BMY

16 Nígbà tí ìròyìn náà dé ààfin Fáráò pé àwọn arákùnrin Jósẹ́fù dé, inú Fáráò àti àwọn ìjòyè rẹ̀ dùn.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 45

Wo Jẹ́nẹ́sísì 45:16 ni o tọ