Jẹ́nẹ́sísì 45:17 BMY

17 Fáráò wí fún Jósẹ́fù pé, “Wí fún àwọn arákùnrin rẹ pé, ‘Èyí ni kí ẹ ṣe: Ẹ di ẹrù lé ẹranko yín kí ẹ sì padà sí ilẹ̀ Kénánì,

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 45

Wo Jẹ́nẹ́sísì 45:17 ni o tọ