Jẹ́nẹ́sísì 48:22 BMY

22 Pẹ̀lúpẹ̀lú èmi yóò fún ọ ní ìpín kan ju ti àwọn arákùnrin rẹ lọ. Ilẹ̀ tí mo fi idà àti ọ̀kọ̀ mi gbà lọ́wọ́ àwọn ará Ámórì.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 48

Wo Jẹ́nẹ́sísì 48:22 ni o tọ