Jẹ́nẹ́sísì 49:1 BMY

1 Nígbà náà ni Jákọ́bù ránṣẹ́ pe àwọn ọmọ rẹ̀, ó sì wí pé, “Ẹ kó ara yín jọ pọ̀, kí n le è sọ ohun tí yóò sẹlẹ̀ ní ọjọ́ iwájú fún-un yín.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 49

Wo Jẹ́nẹ́sísì 49:1 ni o tọ