Jẹ́nẹ́sísì 49:4 BMY

4 Ẹni ríru bí omi òkun, ìwọ kì yóò tayọ mọ́,nítorí pé ìwọ gun ibùsùn baba rẹ,lórí àkéte mi, ìwọ sì bà á jẹ́(ìwọ bá ọ̀kan nínú àwọn aya baba rẹ lò pọ̀).

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 49

Wo Jẹ́nẹ́sísì 49:4 ni o tọ