Jẹ́nẹ́sísì 50:8 BMY

8 Yàtọ̀ fún gbogbo àwọn ará ilé Jóṣẹ́fù àti ti àwọn arákùnrin rẹ̀ àti àwọn tí ó jẹ́ ilé baba rẹ̀, àwọn ọmọ wọn nìkan àti agbo ẹran pẹ̀lú agbo màlúù ni ó sẹ́ kù ní Gósénì.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 50

Wo Jẹ́nẹ́sísì 50:8 ni o tọ