Jẹ́nẹ́sísì 7:11 BMY

11 Ní ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù kéjì, tí Nóà pé ọmọ ẹgbẹ̀ta ọdún, ni gbogbo ìṣun ibú ya, fèrèsé ìṣàn omi ọ̀run sì sí sílẹ̀.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 7

Wo Jẹ́nẹ́sísì 7:11 ni o tọ