Jẹ́nẹ́sísì 7:6 BMY

6 Nóà jẹ́ ọmọ ẹgbẹ̀ta ọdún nígbà tí ìkún omi dé sórí ilẹ̀.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 7

Wo Jẹ́nẹ́sísì 7:6 ni o tọ