Jẹ́nẹ́sísì 8:12 BMY

12 Nóà tún mú sùúrù fún ọjọ́ méje, ó sì tún rán àdàbà náà jáde, ṣùgbọ́n àdàbà náà kò padà sọ́dọ̀ rẹ̀ mọ́.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 8

Wo Jẹ́nẹ́sísì 8:12 ni o tọ