Jẹ́nẹ́sísì 8:13 BMY

13 Ní ọjọ́ kìn-ín-ní oṣù kìn-ín-ní, ní ọdún kọ́kànlélẹ́gbẹ̀ta (601) ni omi náà gbẹ kúrò lórí ilẹ̀; Nóà sì sí ọkọ̀, ó sì ri pé ilẹ̀ ti gbẹ.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 8

Wo Jẹ́nẹ́sísì 8:13 ni o tọ