Jẹ́nẹ́sísì 9:16 BMY

16 Nígbàkígbà tí òsùmàrè bá yọ ní ojú ọ̀run, èmi yóò rí i, èmi yóò sì rántí májẹ̀mú ayérayé tí ń bẹ láàrin Ọlọ́run àti gbogbo ẹ̀dá alààyè tí ń bẹ ní ayé.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 9

Wo Jẹ́nẹ́sísì 9:16 ni o tọ