Jẹ́nẹ́sísì 9:17 BMY

17 Ọlọ́run sì wí fún Nóà pé, “Èyí ni àmì májẹ̀mú tí mo ti fi ìdí rẹ̀ múlẹ̀ láàrin èmi àti gbogbo alààyè ní ayé.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 9

Wo Jẹ́nẹ́sísì 9:17 ni o tọ