O. Daf 101:6 YCE

6 Oju mi yio wà lara awọn olõtọ, ki nwọn ki o le ma ba mi gbe: ẹniti o ba nrìn li ọ̀na pipé, on ni o ma sìn mi.

Ka pipe ipin O. Daf 101

Wo O. Daf 101:6 ni o tọ