1 Ẹ ma yìn Oluwa, ẹnyin orilẹ-ède gbogbo: ẹ yìn i, ẹnyin enia gbogbo.
2 Nitoriti iṣeun ãnu rẹ̀ pọ̀ si wa: ati otitọ Oluwa duro lailai. Ẹ yìn Oluwa!