O. Daf 103:17 YCE

17 Ṣugbọn ãnu Oluwa lati aiyeraiye ni lara awọn ti o bẹ̀ru rẹ̀, ati ododo rẹ̀ lati ọmọ de ọmọ:

Ka pipe ipin O. Daf 103

Wo O. Daf 103:17 ni o tọ