16 Oluwa nitõtọ iranṣẹ rẹ li emi; iranṣẹ rẹ̀ li emi, ati ọmọ iranṣẹ-birin rẹ: iwọ ti tú ìde mi.
Ka pipe ipin O. Daf 116
Wo O. Daf 116:16 ni o tọ