1 NINU ipọnju mi emi kepè Oluwa, o si da mi lohùn.
2 Oluwa, gbà ọkàn mi, lọwọ ète eke, ati lọwọ ahọn ẹ̀tan?
3 Kini ki a fi fun ọ? tabi kini ki a ṣe si ọ, ahọn ẹ̀tan.
4 Ọfà mimu alagbara, ti on ti ẹyin-iná igi juniperi!
5 Egbe ni fun mi, ti mo ṣe atipo ni Meṣeki, ti mo joko ninu agọ Kedari!