3 Kini ki a fi fun ọ? tabi kini ki a ṣe si ọ, ahọn ẹ̀tan.
4 Ọfà mimu alagbara, ti on ti ẹyin-iná igi juniperi!
5 Egbe ni fun mi, ti mo ṣe atipo ni Meṣeki, ti mo joko ninu agọ Kedari!
6 O ti pẹ ti ọkàn mi ti ba ẹniti o korira alafia gbe.
7 Alafia ni mo fẹ: ṣugbọn nigbati mo ba sọ̀rọ, ija ni ti wọn.