6 Gbadura fun alafia Jerusalemu: awọn ti o fẹ ọ yio ṣe rere.
7 Ki alafia ki o wà ninu odi rẹ, ati ire ninu ãfin rẹ.
8 Nitori awọn arakunrin ati awọn ẹgbẹ mi, emi o wi nisisiyi pe, Ki alafia ki o wà ninu rẹ!
9 Nitori ile Oluwa Ọlọrun wa, emi o ma wá ire rẹ.