2 Emi o ti ma gbìmọ li ọkàn mi pẹ to? ti emi o ma ni ibinujẹ li ọkàn mi lojojumọ? ọta mi yio ti gberaga sori mi pẹ to?
Ka pipe ipin O. Daf 13
Wo O. Daf 13:2 ni o tọ