O. Daf 132:9 YCE

9 Ki a fi ododo wọ̀ awọn alufa rẹ: ki awọn enia mimọ rẹ ki o ma hó fun ayọ̀.

Ka pipe ipin O. Daf 132

Wo O. Daf 132:9 ni o tọ