1 AṢIWERE wi li ọkàn rẹ̀ pe, Ọlọrun kò si. Nwọn bajẹ, nwọn si nṣe iṣẹ irira, kò si ẹniti nṣe rere.
Ka pipe ipin O. Daf 14
Wo O. Daf 14:1 ni o tọ