O. Daf 148:13 YCE

13 Ki nwọn ki o ma yìn orukọ Oluwa; nitori orukọ rẹ̀ nikan li o li ọlá; ogo rẹ̀ bori aiye on ọrun.

Ka pipe ipin O. Daf 148

Wo O. Daf 148:13 ni o tọ