O. Daf 149:5 YCE

5 Jẹ ki awọn enia mimọ́ ki o kún fun ayọ̀ ninu ogo; ki nwọn ki o mã kọrin kikan lori ẹni wọn.

Ka pipe ipin O. Daf 149

Wo O. Daf 149:5 ni o tọ