O. Daf 19:1 YCE

1 AWỌN ọrun nsọ̀rọ ogo Ọlọrun; ati ofurufu nfi iṣẹ ọwọ rẹ̀ han.

Ka pipe ipin O. Daf 19

Wo O. Daf 19:1 ni o tọ