O. Daf 20:5 YCE

5 Awa o ma kọrin ayọ̀ igbala rẹ, ati li orukọ Ọlọrun wa li awa o fi ọpágun wa de ilẹ; ki Oluwa ki o mu gbogbo ibère rẹ ṣẹ.

Ka pipe ipin O. Daf 20

Wo O. Daf 20:5 ni o tọ