O. Daf 35:15 YCE

15 Ṣugbọn ninu ipọnju mi nwọn yọ̀, nwọn si kó ara wọn jọ: awọn enia-kenia kó ara wọn jọ si mi, emi kò si mọ̀; nwọn fa mi ya, nwọn kò si dakẹ.

Ka pipe ipin O. Daf 35

Wo O. Daf 35:15 ni o tọ