O. Daf 37:14 YCE

14 Awọn enia buburu ti fà idà yọ, nwọn si ti fà ọrun wọn le, lati sọ talaka ati alaini kalẹ, ati lati pa iru awọn ti nrin li ọ̀na titọ.

Ka pipe ipin O. Daf 37

Wo O. Daf 37:14 ni o tọ