O. Daf 4:1 YCE

1 GBOHÙN mi nigbati mo ba npè, Ọlọrun ododo mi: iwọ li o da mi ni ìde ninu ipọnju; ṣe ojurere fun mi, ki o si gbọ́ adura mi.

Ka pipe ipin O. Daf 4

Wo O. Daf 4:1 ni o tọ