1 ỌLỌRUN, awa ti fi eti wa gbọ́, awọn baba wa si ti sọ fun wa ni iṣẹ́ nla ti iwọ ṣe li ọjọ wọn, ni igbà àtijọ́.
Ka pipe ipin O. Daf 44
Wo O. Daf 44:1 ni o tọ