17 Gbogbo wọnyi li o de si wa; ṣugbọn awa kò gbagbe rẹ, bẹ̃li awa kò ṣe eke si majẹmu rẹ.
Ka pipe ipin O. Daf 44
Wo O. Daf 44:17 ni o tọ