8 Gbẹkẹle e nigbagbogbo; ẹnyin enia, tú ọkàn nyin jade niwaju rẹ̀; Ọlọrun àbo fun wa.
Ka pipe ipin O. Daf 62
Wo O. Daf 62:8 ni o tọ