O. Daf 66:3 YCE

3 Ẹ wi fun Ọlọrun pe, Iwọ ti li ẹ̀ru to ninu iṣẹ rẹ! nipa ọ̀pọ agbara rẹ li awọn ọta rẹ yio fi ori wọn balẹ fun ọ.

Ka pipe ipin O. Daf 66

Wo O. Daf 66:3 ni o tọ