O. Daf 70:4 YCE

4 Ki gbogbo awọn ti nwá ọ ki o ma yọ̀, ki inu wọn ki o si ma dùn nipa tirẹ: ki iru awọn ti o si fẹ igbala rẹ ki o ma wi nigbagbogbo pe, Ki a gbé Ọlọrun ga!

Ka pipe ipin O. Daf 70

Wo O. Daf 70:4 ni o tọ