O. Daf 72:9 YCE

9 Awọn ti o joko li aginju yio tẹriba fun u; awọn ọta rẹ̀ yio si lá erupẹ ilẹ.

Ka pipe ipin O. Daf 72

Wo O. Daf 72:9 ni o tọ