O. Daf 77:2 YCE

2 Li ọjọ ipọnju mi emi ṣe afẹri Ọlọrun: ọwọ mi nnà li oru, kò si rẹ̀ silẹ: ọkàn mi kọ̀ ati tù ninu.

Ka pipe ipin O. Daf 77

Wo O. Daf 77:2 ni o tọ